352 Yoruba Proverbs Sayings And Translations - Yoruba Project 330 - 339 Adebanji Osanyingbemi - Olayinka Carew - Jack Lookman - ede Yoruba
330. Kò sí oun tí ádíyẹ̀ lẹ́ fì ọ̀mọ́ àṣá ṣẹ́ Buy - 352 Yoruba Proverbs Sayings And Translations - Yoruba Project - https://amzn.to/4cTuyMl There is nothing the hen can do with the offspring of the hawk There is nothing you can do humanly to someone more powerful than you 331. Àbọ ọrọ là á n sọ fun ọmọlúwàbí. Tó bá dé inu rẹ á di odidi. We speak half of a word to the child born of honour. It becomes a whole in him when he digests it. Half a word is enough for the wise. 332. ìwó tà n wó àpáró bí kà fí dálá, òrí ẹ́yẹ̀ ní o pa ẹ́yẹ̀ The way we stare at the partridge is to make an okra soup with it but it's creator will not make it happen Complete Yoruba Course For Beginners - https://amzn.to/4dUeGKg No matter the intention of people towards one the Almighty will always prevail 333. Àdábà n pe ógèdè, ó sèbi ẹyẹ̀lé ó gbọ́, ẹyẹ̀lẹ́ gbọ́ titiri ni o ntiri The dove is reciting incantations, thinking the pigeon does not understand, the pigeon understands...