Posts

352 Yoruba Proverbs, Sayings And Translations - Yoruba Project - 190 - 199 - #AdebanjiOsanyingbemi #OlayinkaCarew #edeYoruba #oweYoruba

  190. Ọmọrí odó pani lọ́tọ̀, ká tó wí pé ká kùn ún lóògùn. A pestle is a lethal weapon in itself, let alone after rubbing poison on it. Overkill is pointless. Also, if a situation is dangerous enough as it is, one should not aggravate it by acting provocatively. 191. Ọlọ́dẹ kì í torí atẹ́gùn yìnbọn. A hunter does not fire off his gun because of the wind. One should be deliberate and attentive in pursuing one's profession. 192. Oníbàtà ló ńfojú di ẹ̀gún; ẹni táa bá fẹ́ ló ńfojú dini.  Those with shoes easily despise thorns; those we love easily take us for granted. Knowledge breeds power and disarms fear; we hardly fear who or what we know inside out! 193. Kùkùté kan kì í fọ́ni lépo lẹ́ẹ̀mejì. No one stump can break one's oil-pot twice. The same disaster should not befall a person twice; one usually learns from experience. 194. Kọ́kọ́rọ́ àṣejù, ilẹ̀kùn ẹ̀tẹ́ la fi ńṣí. The key of excess is usually good only to open the door of disgrace. Excess b

352 Yoruba Proverbs, Sayings And Translations - Yoruba Project - 180 - 189 - #AdebanjiOsanyingbemi #OlayinkaCarew #oweYoruba #edeYoruba

  180. Ta leṣinṣin ìbá gbè bí kò ṣe elégbò? Who else will the flies flock after if not the person with open sores. Opportunistic people can be expected to stick with those who offer them the most benefits. 181. Ẹni tí ó bá mọ ìṣe òkùnkùn, kó má dàá òṣùpá lóró; ohun a ṣe ní ńmúni-í rìnde òru; òkùnkùn ò yẹ ọmọ èèyàn. Whoever knows what darkness can do must not antagonize the moon; one's actions “sometimes” send one abroad at night; roaming around in the dark is not a becoming habit. It is best to cultivate those forces that might serve one well in the future. 182. Ẹni tí a nà ní kùm̀mọ̀ mẹ́fà, tó ní ọ̀kan ṣoṣo ló ba òun, níbo nìyókùú sọnù sí? A person who is hit six times with a club and says only one blow landed; where did the other blows disappear to? A person who tries to minimize his or her obvious misfortune deceives no one. 183. Íso ó làatan, kò sí a dára máa sú. Ọ̀mọ́ Òyìnbó nyàgbẹ̀. Fart has no waste-bin, defecating has nothing to do with beauty. The W